
Barry Jhay Lyrics
Embrace the power of words and music with the heartfelt lyrics of Barry Jhay’s Eleduwa.


Barry Jhay – Eleduwa Lyrics
IntroOjo buruku lonisotun’unBaba sho’n gbo oun aiye’n soEledua.. eyin ni akoko ninu gbogbo nkanKeto da aye ati orunAnd that na why me I put you first in everything I doO’ma ma se olorun miOpo opo ooo
ChorusIbi tan ni ki gbegbe magbe, lofi shey aparteyIbi tan ni ki tete màté lò ló shey vaceyNigba tan tu wa’n soro, woni mio mo ju’olorun loBaba sho’ngbo oun aiye soAyun lo, ayun bo lowo yun enuIko o’ni ko bàlà mi lè se Ni ola olorunLa tio ni lo, ki onaa mi kola peregedeLa to ni lo, magbe ori ile yii seun rere
VerseEyin to laye!E gbo oun mi se ase IFA Abiyamo aiye!!E duro timi ki’n mase jabo ooIkoko lafi de’e Lodo IFA oooKaraye mafowo bo agogo mi lenu eeTi’n ba lu se ni koma dun’n
ChorusIbi tan ni ki gbegbe magbe, lofi shey aparteyIbi tan ni ki tete màté lò ló shey vaceyNigba tan tu wa’n soro, woni mio mo ju’olorun loBaba sho’ngbo oun aiye soAyun lo, ayun bo lowo yun enuIko o’ni ko bàlà mi lè sé, ni ola olorunLa tio ni lo, ki onaa mi kola peregedeLa to ni lo, magbe ori ile yii seun rere
OutroLa tio ni lo, ki onaa mi kola peregedeLa to ni lo, magbe ori ile yii seun rere
Want to keep up with the latest songs? Check out more song lyrics here and follow us on X and Facebook