Pelumi Deborah and George Alao Lyrics
Read the lyrics below and sing along to Omo’ba captivating melodies by Pelumi Deborah, featuring George Alao.
Pelumi Deborah & George Alao – Omo’ba Lyrics
Seb’ emi na re o, omo ObaAlemi na re o, omo ObaAlemi na re o, omo ObaWhy look any furtherSeb’ emi na re o, omo Oba
Eni Oba nkeEni Oba ngeEni Oba n woEni Oba ntojuOba lo to mi dagbaOba lo womi dagbaOba lo ran mi ni şeOba lo f’ ami simi LaraOba lo da ororo lemi loriO f’ade iyin de mi loriO f’ ade ogo demi loriO f’ ade ewa demi lori
Ohun lo ni ki n duro deedeOlohun wa lehin mi bi akoni eleruO ni awon omo kiniunWon a ma se alainiEbi a si maa pawonSugbon awon to duro de Oluwawon ko ni s’ alaini ohun to daraEmi ti gbe Oluwa ka iwaju mi nigbagbogboNitori O wa lehin mi ehAki yio si mi nipo
Won o le si mi nipo ehMo ni won o le si mi nipoEmi o see si nipoTori Oba lo ran mi nise, eh!Oba lo ran mi nise
Baa ranni nise Oba aa fi toba jeBaa ranni nise Oba aa fi toba jeOba lo ran mi niseOhun lo ni ki n ma beruOhun loni ki n ma foyaOhun lo ni ki n te siwaju
Seb’ emi naa re oo, omo ObaA lemi naa re o om’ ObaI can’t help itSeb’ emi naa re oo eeehhhhSeb’ emi naa re o om’ Oba o ehSeb’ emi naa re omoSeb’ emi naa re oo
AjikeAjigeApekeAsakeAyanfe
Ololufe mi lo pemiO ni kin duro deedeO ni kin mase beruO ni kin mase foyaSeb’ emi na reOmo’ baSeb’ emi na reOmo’ baSeb’ emi na reOmo’ baSeb’ emi na reOmo’ ba
Omo’ba ni e mase beruOmo’ba ni e mase foya
Seb’ emi naa re oo, omo ObaA lemi naa re o om’ ObaI like this song
Oba nke miOba n wo miOba lo n dari ese miEmi naa re omo’ baOba nke miOba n wo miOba lo n dari ese miEmi naa re omo’ baOba nkę miOba n wo mi dagbaOba lo n dari ese miEmi naa re omo’ baOne more timeOba nke miOba n wo miOba lo n dari miEmi naa re omo’ baOba nke miOba n lo ni kin ma beeruOba lo n dari ese miEmi naa re omo’ baOba nke miOba n wo miOba lo n dari ese miEmi naa re omo’ ba
Tori onawo ife si miTori onawo iye si miTori onawo ayo si mi…
Want to keep up with trending songs? Check out more song lyrics here and follow us on X and Facebook