Barry Jhay Lyrics
Embrace the power of words and music with the heartfelt lyrics of Barry Jhay’s See Me See God. See Me See God is the ninth track on Barry’s latest album, Barrystar Vol.1.

Barry Jhay – See Me See God Lyrics
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duroỌrọ mi d’akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutuKoda, ko ṣe China t’ọn gbe ti n jẹ wọnẸni j’alangba n tutu, a ko warapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ahYeah, ay-ya-ay, ah-ah, ahOh-wa, oh, wa-wa-wa(Nobody’s perfect)
Yea, ki’ku ma-ma pa awọn to gbe mi s’ori bi geleKi ibaunjẹ jina siwa rere, ay, tefe-tefeKi’ku maa p’ọta mi, ko le riran-wo(O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)Ki’ku maa p’ọta mi, ko le riran-wo(Mo ṣi n m’ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
If I see say wahala don dey too muchNa to roll up a big fat one, motivation gan-an ti n pa’yan, wahala nikan kọ oIka ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọỌmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeahṢe you dey see level o?Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, as I dey find wetin I go chop, ooh-iy-iyMake I no jam wetin go chop meOluwa lo gbe (yea-yea), lo gbe mi sokeEmi ko le ṣa i ṣọpẹ
See me, see God o, abi emi naa kọỌmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeahṢe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)Yeah, o loju ọmọ to damọ
If I see say wahala don dey too muchNa to roll up a big fat one, motivation gan-an ti n pa’yan, wahala nikan kọ oIka ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọỌmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeahṢe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)Yeah, o loju ọmọ to damọ
(Sunshine)
Check Lyrics of latest songs here, and get fresh updates as they drop via X and Facebook